Ẹ Pàdé Omọ́wálé, Tó Há Awọn Iwé Itàn D. O. Fágúnwà Sórí: Èdè Wa Ni | Duduspree FM Radio
images 3 1
By Cypher Ilerioluwa

Duduspree News, Texas


Duduspree News is not responsible for the content of external sites.

View original tweet on Twitter

A ṣe àbẹ̀wò sí bàbá Ọmọ́wálé Òdúmọ ti wọ́n há àwọn ìwé márààrún òǹkọ̀wé ìtàn àròsọ méríìírí ìgbàanì sórí, tí wọ́n sí ń kà wọ́n sí etígbọ̀ọ́ àwọn ènìyàn lóòrèkóòrè láti kọ́ ẹ̀kọ́ nínú wọn àti láti dá wọn lára yá.

Bàbá sọ bí ìrìnàjò ẹ̀kọ́ wọn ṣe bẹ̀rẹ̀, wọ́n sì ṣàlàyé pé ẹ̀bùn àmútọ̀runwá lásán ni híhá nǹkan sórí jẹ́ fáwọn, àwọn ò múkan mọ́kan rárá.

Written by:

Cypher Ilerioluwa is a skilled and experienced professional in social media management, blogging, content creation, animation and web design.

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

X